Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ Sámúẹ́lì tọ gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá.Nísinsìnyìí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde láti lọ bá àwọn Fílístínì jà. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì pàgọ́ sí Ebenésérì àti àwọn Fílístínì ní Áfékì.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 4

Wo 1 Sámúẹ́lì 4:1 ni o tọ