Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 29:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́, nísinsin yìí dìde ní òwúrọ pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ olúwa rẹ tí ó bá ọ wá: ki ẹ si dìde ní òwúrọ̀ nígbà tí ilẹ̀ bá mọ́ kí ẹ sì máa lọ.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 29

Wo 1 Sámúẹ́lì 29:10 ni o tọ