Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 29:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn Fílístínì sì kó gbogbo ogun wọn jọ sí Áfékì: Ísírẹ́lì sì dó ni ibi ìsun omi tí ó wà ní Jésírélì.

2. Àwọn ìjòyé Fílístínì sì kọjá ní ọ̀rọ̀ọ̀rún àti lẹ́gbẹgbẹ̀rún; Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ pẹ̀lú Ákíṣì sì kẹ́yìn.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 29