Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 26:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì dáhùn, ó sì wí fún Áhímélékì, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ Hétì, àti fún Ábíṣáì ọmọ Sérúíà ẹ̀gbọ́n Jóábù, pé, “Ta ni yóò ba mi sọ̀kalẹ̀ lọ sọ́dọ̀ Ṣọ́ọ̀lù ni ibùdó?”Ábíṣáì sì wí pé, “Èmi yóò ba ọ sọ̀kalẹ̀ lọ.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 26

Wo 1 Sámúẹ́lì 26:6 ni o tọ