Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 25:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábígáílì sì yára, ó sì dìde, ó sì gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àwọn iránṣẹ́bìnrin rẹ̀ márùnún sì tẹ̀lé e lẹ́yìn; oun sì tẹ̀lé àwọn ìránṣẹ́ Dáfídì, o sì wá di aya rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 25

Wo 1 Sámúẹ́lì 25:42 ni o tọ