Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 23:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì lọ sí Kéílà, wọ́n sì bá àwọn ará Fílístínì jà, wọ́n sì kó ohun ọ̀sìn wọn, wọ́n sì fi ìparun ńlá pa wọ́n. Dáfídì sì gba àwọn ará Kéílà sílẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 23

Wo 1 Sámúẹ́lì 23:5 ni o tọ