Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 23:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì tún béèrè lọ́dọ Olúwa. Olúwa sì dá a lóhùn, ó sì wí pé, “Dìde, kí o sọ̀kalẹ̀ lọ sí Kéílà, nítorí pé èmi ó fi àwọn ará Fílístínì náà lé ọ lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 23

Wo 1 Sámúẹ́lì 23:4 ni o tọ