Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 20:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó si wí fún ọmọdékùnrin rẹ̀ pé, “Sáré, kí o si wá àwọn ọfà tí èmi ó ta.” Bí ọmọdé náà sì ti ń sáré, òun sì tafà rékọjá rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20

Wo 1 Sámúẹ́lì 20:36 ni o tọ