Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 20:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Jónátanì sì fi ìbínú dìde kúrò ni ibi oúnjẹ, kò sì jẹun ni ọjọ́ kejì oṣù náà, inú rẹ̀ sì bàjẹ́ gidigidi fún Dáfídì, nítorí pé baba rẹ̀ dójú tì í.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20

Wo 1 Sámúẹ́lì 20:34 ni o tọ