Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 20:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì dáhùn pé, “Kí a má rí i! Ìwọ kò ní kú! Wò ó baba mi kì í ṣe ohunkóhun tí ó tóbi tàbí tí ó kéré, láì fi lọ̀ mí. Èéṣe tí yóò fi fi èyí pamọ́ fún mi? Kò rí bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20

Wo 1 Sámúẹ́lì 20:2 ni o tọ