Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 20:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jónátanì sọ fún Dáfídì: “Pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run àwọn Ísírẹ́lì, èmi yóò rí i dájú pé mo gbọ́ ti ẹnu baba mi ní ìwòyí ọ̀la tàbí ní ọ̀túnla tí ó bá sì ní ojú rere ní inú dídùn sí ọ, tí èmi kò bá ránṣẹ́ sí ọ, kí èmi sì jẹ́ kí o mọ̀?

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20

Wo 1 Sámúẹ́lì 20:12 ni o tọ