Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì sọ̀rọ̀ rere nípa Dáfídì fún Ṣọ́ọ̀lù baba rẹ̀, ó sì wí fún un pé, “Má ṣe jẹ́ kí ọba kí ó ṣe ohun tí kò dára fún Dáfídì ìránṣẹ́ rẹ̀; nítorí tí kò ṣẹ̀ ọ́, ohun tí ó sì ṣe pé ọ púpọ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 19

Wo 1 Sámúẹ́lì 19:4 ni o tọ