Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 19:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù wí fún Míkálì pé, “Èéṣe tí ìwọ fi tàn mí báyìí tí o sì jẹ́ kí ọ̀ta mi sálọ tí ó sì bọ́?”Míkálì sọ fún un pé, “Ó wí fún mi, jẹ́ kí èmi ó lọ. Èéṣe tí èmi yóò fi pa ọ́?”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 19

Wo 1 Sámúẹ́lì 19:17 ni o tọ