Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 17:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti ọwọ́ sí àpò rẹ̀ ó sì mú òkúta jáde wá ó sì fì í, ó sì jù ú sí ọ̀kọ́kán iwájú orí Fílístínì. Òkúta náà sì wọ̀ ọ́ níwájú orí, ó sì ṣubú ó sì dojúbolẹ̀ ní orí ilẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 17

Wo 1 Sámúẹ́lì 17:49 ni o tọ