Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 15:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ ogun ti mú àgùntàn àti màlúù lára ìkógùn èyí tí ó dára láti fi fún Olúwa láti fi rúbọ sí Olúwa Ọlọ́run rẹ ní Gílígálì.”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 15

Wo 1 Sámúẹ́lì 15:21 ni o tọ