Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì wí fún Sámúẹ́lì pé, “Ṣùgbọ́n èmi ti ṣe ìgbọ́rán sí Olúwa, èmi sì ti lọ ní ọ̀nà tí Olúwa rán mi. Mo sì ti pa àwọn ará Ámálékì run pátapáta, mo sì ti mú Ágágì ọba wọn padà wá.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 15

Wo 1 Sámúẹ́lì 15:20 ni o tọ