Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lẹ́yìn náà, ìwọ yóò lọ sí òkè Ọlọ́run, níbi tí ẹgbẹ́ ogun àwọn Fílístínì wà. Bí ìwọ ti ń súnmọ́ ìlú náà, ìwọ yóò bá àwọn wòlíì tí ó tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ bọ̀ láti ibi gíga, pẹ̀lú líárì, támborí àti fèrè àti gìta níwájú wọn, wọn yóò sì máa sọ àṣọtẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 10

Wo 1 Sámúẹ́lì 10:5 ni o tọ