Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ilé yìí tí ó ga, ẹnu yóò sì ya olúkúlùkù ẹni tí ó kọjá lẹ́bàá rẹ̀, yóò sì pòṣé, wọn ó sì wí pé, ‘Èéṣe tí Olúwa fi ṣe irú nǹkan yìí sí ilẹ̀ yìí àti ilé yìí?’

Ka pipe ipin 1 Ọba 9

Wo 1 Ọba 9:8 ni o tọ