Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà náà ni èmi yóò ké Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ tí èmi fi fún wọn, èmi yóò sì kọ ilé yìí tí èmi ti yà sí mímọ́ fún orúkọ mi. Nígbà náà ni Ísírẹ́lì yóò sì di òwe àti ìmúṣẹ̀sín láàrin gbogbo orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin 1 Ọba 9

Wo 1 Ọba 9:7 ni o tọ