Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:59 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti kí ó sì jẹ́ kí àwọn ọ̀rọ̀ mi wọ̀nyí, tí mo ti gbà ní àdúrà níwájú Olúwa, kí ó wà nítòsí Olúwa Ọlọ́run wa ní ọ̀sán àti ní òru, kí ó lè mú ọ̀rọ̀ ìránṣẹ́ rẹ̀ dúró àti ọ̀rọ̀ Ísírẹ́lì ènìyàn rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí àìní wa ojoojúmọ́,

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:59 ni o tọ