Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 8:58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó fa ọkàn wa sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀, láti máa rìn nínú gbogbo ọ̀nà rẹ̀, àti láti pa òfin rẹ̀ mọ́, àti àṣẹ rẹ̀, àti ìlànà rẹ̀, tí ó ti pàṣẹ fún àwọn bàbá wa.

Ka pipe ipin 1 Ọba 8

Wo 1 Ọba 8:58 ni o tọ