Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dá ọ̀wọ̀n idẹ méjì, ọ̀kọ̀ọ̀kan sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ méjìdínlógún ní gíga okùn ìgbọ̀nwọ́ méjìlá ni ó sì yí wọn ká.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:15 ni o tọ