Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 7:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹni tí ìyá rẹ̀ jẹ́ opó láti inú ẹ̀yà Náfítalì àti tí baba rẹ̀ sì ṣe ará Tírè, alágbẹ̀dẹ idẹ. Hírámù sì kún fún ọgbọ́n àti òye, àti ìmọ̀ láti ṣe oríṣiríṣi iṣẹ́ idẹ. Ó wá sọ́dọ̀ Sólómónì ọba, ó sì ṣe gbogbo iṣẹ́ tí wọ́n gbé fún un.

Ka pipe ipin 1 Ọba 7

Wo 1 Ọba 7:14 ni o tọ