Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 6:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yàrá ìsàlẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn ún ní ìbú, ti àárin sì jẹ́ ìgbọ̀wọ́ mẹ́fà ní ìbú, àti ẹ̀kẹta ìgbọ̀nwọ́ méje sì ni ìbú rẹ̀. Nítorí lóde ilé náà ni ó dín ìgbọ̀nwọ́ kọ́ọ̀kan káàkiri, kí igi àjà kí ó má ba à wọ inú ògiri ilé náà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 6

Wo 1 Ọba 6:6 ni o tọ