Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Níti ilé yìí tí ìwọ ń kọ́ lọ́wọ́, bí ìwọ bá tẹ̀lé àṣẹ mi, tí ìwọ sì ṣe ìdájọ́ mi, tí o sì pa òfin mi mọ́ láti máa ṣe wọ́n, Èmi yóò mú ìlérí tí mo ti ṣe fún Dáfídì baba rẹ̀ ṣẹ nípa rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 6

Wo 1 Ọba 6:12 ni o tọ