Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin kejì sì wí pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́! Èyí alààyè ni ọmọ mi, èyí òkú ni ọmọ tirẹ̀.” Èyí òkú ni tirẹ̀; èyí alààyè ni tèmi.Ṣùgbọ́n èyí àkọ́kọ́ tún wí pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́! Èyí òkú ni tìrẹ; èyí alààyè ni tèmi.” Báyìí ni wọ́n sì ń jiyàn níwájú ọba.

Ka pipe ipin 1 Ọba 3

Wo 1 Ọba 3:22 ni o tọ