Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ísírẹ́lì dá Jèhóṣáfátì lóhùn pé, “Ọkùnrin kan sì wà, lọ́dọ̀ ẹni tí àwa lè béèrè lọ́wọ́ Olúwa, ṣùgbọ́n mo kórìíra rẹ̀ nítorí kì í sọ àsọtẹ́lẹ̀ rere kan nípa mi, bí kò ṣe ibi. Míkáyà ọmọ Ímílà ni.”Jéhósáfátì sì wí pé, “Kí ọba má ṣe sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:8 ni o tọ