Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà náà Áhásáyà ọmọ Áhábù wí fún Jáhósáfátì pé, “Jẹ́ kí àwọn ìránṣẹ́ mi bá àwọn ìránṣẹ́ rẹ lọ nínú ọkọ̀,” ṣùgbọ́n Jèhósáfátì kọ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:49 ni o tọ