Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níti ìyókù ìṣe Áhábù, àti gbogbo èyí tí ó ṣe, àti ilé eyin-erin tí ó kọ́, àti gbogbo ìlú tí ó tẹ̀dó, a kò ha kọ wọ́n sínú ìwé ọ̀rọ̀ ọjọ́ àwọn ọba Ísírẹ́lì?

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:39 ni o tọ