Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ísírẹ́lì sì wí fún Jèhósáfátì pé, “Èmi yóò pa aṣọ dà, èmi yóò sì lọ sí ojú ìjà, ṣùgbọ́n ìwọ yóò wọ aṣọ ìgúnwà rẹ.” Bẹ́ẹ̀ ni ọba Ísírẹ́lì pa aṣọ dà, ó sì lọ sí ojú ìjà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:30 ni o tọ