Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ísírẹ́lì sì ti wí fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, “Ǹjẹ́ ẹ̀yin mọ̀ pé ti wa ni Ramoti Gílíádì, àwa sì dákẹ́ síbẹ̀, a kò sì gbà á padà lọ́wọ́ ọba Árámù?”

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:3 ni o tọ