Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olúwa sì béèrè pé, ‘Báwo?’ Ó sì wí pé,“ ‘Èmi yóò jáde lọ, èmi yóò sì di ẹ̀mí èké ní ẹnu gbogbo àwọn wòlíì rẹ̀.’“Olúwa sì wí pé, ‘Ìwọ yóò tàn án, ìwọ yóò sì borí, jáde lọ, kí o sì ṣe bẹ́ẹ̀.’

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:22 ni o tọ