Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìránṣẹ́ tí ó lọ pe Míkáyà wí fún un pé, “Wò ó, ẹnu kan náà ni ọ̀rọ̀ àwọn wòlíì fi jẹ́ rere fún ọba. Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ rẹ bá ti àwọn tókù mu, kí o sì sọ rere.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:13 ni o tọ