Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhábù sì wá sí ilé rẹ̀, ó wugbọ́, inú rẹ̀ sì bàjẹ́ nítorí ọ̀rọ̀ tí Nábótì ará Jésérẹ́lì sọ fún un; nítorí tí ó wí pé, “Èmi kì yóò fún ọ ní ogún àwọn bàbá mi.” Ó sì dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ̀, ó sì yí ojú rẹ̀ padà, kò sì fẹ́ jẹun.

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:4 ni o tọ