Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Áhábù sì gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí, ó sì fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì fi aṣọ ọ̀fọ̀ sí ara rẹ̀, ó sì gba ààwẹ̀. Ó sì dùbúlẹ̀ nínú aṣọ ọ̀fọ̀, ó sì ń lọ jẹ́ ẹ́.

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:27 ni o tọ