Ó sì ṣe ohun ìríra gidigidi ní títọ òrìṣà lẹ́yìn, gẹ́gẹ́ bí gbogbo ohun tí àwọn ará Ámórì ti ṣe, tí Olúwa lé jáde níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.)