Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 20:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹni-Hádádì sì gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí nigbà tí òun àti àwọn ọba ń mu ọtí nínú àgọ́ wọn, ó sì pàṣẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wí pé, “Ẹ tẹgun sí ìlú náà.” Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sì ṣe tan láti kọlu ìlú náà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 20

Wo 1 Ọba 20:12 ni o tọ