Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 2:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì tún wí fún Síméì pé, “Ìwọ mọ̀ ní ọkàn rẹ gbogbo búburú tí ìwọ ti ṣe sí Dáfídì baba mi. Báyìí, Olúwa yóò san gbogbo ìṣe búburú rẹ padà fún ọ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:44 ni o tọ