Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 2:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọjọ́ tí ìwọ bá jáde, tí o sì kọjá pẹ̀tẹ́lẹ̀ Kídírónì, kí ìwọ kí ó mọ̀ dájúdájú pé ìwọ yóò kú; ẹ̀jẹ̀ rẹ yóò sì wà lórí ara rẹ.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:37 ni o tọ