Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 19:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà Jésébélì rán oníṣẹ́ kan sí Èlíjà wí pé, “Kí àwọn òrìṣà kí ó ṣe sí mi àti jù bẹ́ẹ̀ lọ pẹ̀lú, bí èmi kò bá ṣe ẹ̀mí rẹ bí ọ̀kan nínú wọn ní ìwòyí ọ̀la.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 19

Wo 1 Ọba 19:2 ni o tọ