Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhábù sì ti wí fún Ọbadíà pé, “Lọ sí gbogbo ilẹ̀ sí orísun omi gbogbo àti sí ilẹ̀ gbogbo. Bóyá àwa lè rí koríko láti gba àwọn ẹsin àti àwọn ìbááka là, kí a má báà ṣòfò àwọn ẹranko pátapáta.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:5 ni o tọ