Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Jésébélì sì ń pa àwọn wòlíì Olúwa kúrò, Ọbadíà sì mú ọgọ́rùn ún wòlíì, ó sì fi wọ́n pamọ́ sínú ihò òkúta, àádọ́ta ní ihò kọ̀ọ̀kan, ó sì fi àkàrà pẹ̀lú omi bọ́ wọn.

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:4 ni o tọ