Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé Olúwa mi kò ha ti gbọ́ ohun tí mo ṣe nígbà tí Jésébélì ń pa àwọn wòlíì Olúwa? Mo fi ọgọ́rùn ún wòlíì Olúwa pamọ́ sínú ihò òkúta méjì, àràádọ́ta ní ọ̀kọ̀ọ̀kan, mo sì fi omi àti oúnjẹ bọ́ wọn.

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:13 ni o tọ