Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò sì mọ ibi tí ẹ̀mí Olúwa yóò gbé ọ lọ nígbà tí mo bá fi ọ́ sílẹ̀. Bí mo bá lọ, tí mo sì sọ fún Áhábù, tí kò sì rí ọ, òun a sì pa mí. Ṣíbẹ̀ èmi ìránṣẹ́ rẹ bẹ̀rù Olúwa láti ìgbà èwe mi wá.

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:12 ni o tọ