Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe, lẹ́yìn ọjọ́ púpọ̀, ní ọdún kẹta, ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ Èlíjà wá pé: “Lọ, kí o sì fi ara rẹ̀ hàn fún Áhábù, èmi yóò sì rọ òjò sórí ilẹ̀.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:1 ni o tọ