Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 17:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ó sì képe Olúwa wí pé, “Olúwa Ọlọ́run mi, ìwọ ha mú ibi wá bá opó náà pẹ̀lú lọ́dọ̀ ẹni tí èmi ń ṣe àtìpó, nípa pípa ọmọ rẹ̀?”

Ka pipe ipin 1 Ọba 17

Wo 1 Ọba 17:20 ni o tọ