Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 17:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíjà sì wí fún un pé, “Gbé ọmọ rẹ fún mi.” Ó sì yọ ọ́ jáde ní àyà rẹ̀, ó sì gbé e lọ sí iyàrá òkè ilé níbi tí òun ń gbé, ó sì tẹ́ ẹ sí orí ibùsùn tirẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 17

Wo 1 Ọba 17:19 ni o tọ