Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 16:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi ti gbé ọ ga láti inú erùpẹ̀ wá, mo sì fi ọ́ ṣe olórí Ísírẹ́lì ènìyàn mi, ṣùgbọ́n ìwọ sì rìn ní ọ̀nà Jéróbóámù, ó sì mú kí Ísírẹ́lì ènìyàn mi dẹ́ṣẹ̀, láti mú mi bínú nípa ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin 1 Ọba 16

Wo 1 Ọba 16:2 ni o tọ