Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún Olúwa Ọlọ́run rẹ, tí ó ní inú dídùn sí ọ, tí ó sì gbé ọ ka orí ìtẹ́ Ísírẹ́lì. Nítorí tí Olúwa fẹ́ràn Ísírẹ́lì títí láé, ni ó ṣe fi ọ́ jọba, láti ṣe ìdájọ́ àti òdodo.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 10

Wo 1 Ọba 10:9 ni o tọ