Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún wọn pé: “Ẹ mú àwọn ìránṣẹ́ Olúwa yín pẹ̀lú yín kí ẹ sì mú kí Sólómónì ọmọ mi kí ó gun ìbaka mi, kí ẹ sì mú-un sọ̀kalẹ̀ wá sí Gíhónì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:33 ni o tọ